
Nigerian gospel singer and songwriter, Tope Alabi has released “Alagbara” off her album titled “Alagbara“.
The new single is lifted from her forthcoming album titled, “Alagbara”.
The song “Alagbara” is a wonderful number which is a must for your playlist.
Listen and download below:
Watch video below:
LYRICS: Tope Alabi – Alagbara
Alagbara aye
Aye a tan ooo
Eni loni egbo
Awon to shana
Won o si moo
Igba loni igba nlo
Bawo lo si ire
Yo san esan
Ida pani yio ti’da ku o
Olojo die laye
Ma gba ona kan kan
Ofefe laye asan
Maje ko wo e leje
Igba o lo bi orere
O f’ogun odun sebi
Yio fa da gbaro
Ke ya lomo pe otipa
Ida pani yio ti’da ku o