
Gospel music singer, Tope Alabi presents “E Yin Oluwa, Hallelujah” from her album, “Hymnal (Vol. 1)“.
“Hymnal (Vol. 1)” is available to purchase and stream at all major platforms.
Listen Below:
LYRICS:
EYIN OLUWA HALLELUYAH
Verse 1
Eje ka f;ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai
Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah
Verse 2
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun
Verse 3
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo
Verse 4
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo